Alafia ki o ma baa: Iwo sheikh, mo la ala wipe awon posi awon mosalasi ti jona ti awon ile kan si jona.